- 
	                        
            
            Sáàmù 107:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        14 Ó mú wọn jáde nínú òkùnkùn biribiri, Ó sì fa ìdè wọn já.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 142:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        7 Mú mi* jáde kúrò nínú àjà ilẹ̀ Kí n lè máa yin orúkọ rẹ. Kí àwọn olódodo yí mi ká, Nítorí o ti ṣemí lóore. 
 
-