- 
	                        
            
            Àìsáyà 49:8, 9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        8 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Mo dá ọ lóhùn ní àkókò ojúure,*+ Mo sì ràn ọ́ lọ́wọ́ ní ọjọ́ ìgbàlà;+ Mò ń ṣọ́ ọ kí n lè fi ọ́ ṣe májẹ̀mú fún àwọn èèyàn náà,+ Láti tún ilẹ̀ náà ṣe, Láti mú kí wọ́n gba àwọn ohun ìní wọn tó ti di ahoro,+ Àti fún àwọn tó wà nínú òkùnkùn+ pé, ‘Ẹ fara hàn!’ Etí ọ̀nà ni wọ́n ti máa jẹun, Ojú gbogbo ọ̀nà tó ti bà jẹ́* ni wọ́n ti máa jẹko. 
 
-