Àìsáyà 31:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ó mà ṣe fún àwọn tó ń wá ìrànlọ́wọ́ lọ sọ́dọ̀ Íjíbítì o,+Tí wọ́n gbójú lé ẹṣin,+Tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ogun, torí pé wọ́n pọ̀,Àti àwọn ẹṣin ogun,* torí pé wọ́n lágbára. Wọn ò yíjú sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Wọn ò sì wá Jèhófà. Hósíà 1:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ṣùgbọ́n màá ṣàánú ilé Júdà,+ èmi Jèhófà Ọlọ́run wọn á sì gbà wọ́n là;+ mi ò ní fi ọfà* tàbí idà tàbí ogun tàbí àwọn ẹṣin tàbí àwọn agẹṣin gbà wọ́n là.”+
31 Ó mà ṣe fún àwọn tó ń wá ìrànlọ́wọ́ lọ sọ́dọ̀ Íjíbítì o,+Tí wọ́n gbójú lé ẹṣin,+Tí wọ́n gbẹ́kẹ̀ lé kẹ̀kẹ́ ogun, torí pé wọ́n pọ̀,Àti àwọn ẹṣin ogun,* torí pé wọ́n lágbára. Wọn ò yíjú sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì,Wọn ò sì wá Jèhófà.
7 Ṣùgbọ́n màá ṣàánú ilé Júdà,+ èmi Jèhófà Ọlọ́run wọn á sì gbà wọ́n là;+ mi ò ní fi ọfà* tàbí idà tàbí ogun tàbí àwọn ẹṣin tàbí àwọn agẹṣin gbà wọ́n là.”+