- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 9:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        23 Mósè wá na ọ̀pá rẹ̀ sí ọ̀run, Jèhófà sì mú kí ààrá sán, yìnyín bọ́, iná* sọ̀ kalẹ̀, Jèhófà sì ń mú kí òjò yìnyín rọ̀ sórí ilẹ̀ Íjíbítì. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 107:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        25 Bó ṣe fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú kí ìjì máa jà,+ Tó sì ń ru ìgbì òkun sókè. 
 
-