Ẹ́kísódù 15:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ìbẹ̀rù àti jìnnìjìnnì yóò bò wọ́n.+ Ọwọ́ ńlá rẹ yóò mú kí wọ́n dúró sójú kan bí òkúta Títí àwọn èèyàn rẹ yóò fi kọjá, Jèhófà, Títí àwọn èèyàn tí o mú jáde+ yóò fi kọjá.+ Sáàmù 98:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 98 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà,+Nítorí ó ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu.+ Ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, àní apá mímọ́ rẹ̀, ti mú ìgbàlà wá.*+
16 Ìbẹ̀rù àti jìnnìjìnnì yóò bò wọ́n.+ Ọwọ́ ńlá rẹ yóò mú kí wọ́n dúró sójú kan bí òkúta Títí àwọn èèyàn rẹ yóò fi kọjá, Jèhófà, Títí àwọn èèyàn tí o mú jáde+ yóò fi kọjá.+
98 Ẹ kọ orin tuntun sí Jèhófà,+Nítorí ó ti ṣe àwọn ohun àgbàyanu.+ Ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀, àní apá mímọ́ rẹ̀, ti mú ìgbàlà wá.*+