Àìsáyà 43:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹran igbó máa bọlá fún mi,Àwọn ajáko* àti ògòǹgò,Torí mo pèsè omi ní aginjù,Odò ní aṣálẹ̀,+Fún àwọn èèyàn mi, àwọn àyànfẹ́ mi,+ kí wọ́n lè mu,
20 Ẹran igbó máa bọlá fún mi,Àwọn ajáko* àti ògòǹgò,Torí mo pèsè omi ní aginjù,Odò ní aṣálẹ̀,+Fún àwọn èèyàn mi, àwọn àyànfẹ́ mi,+ kí wọ́n lè mu,