Àìsáyà 41:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “Àwọn aláìní àti àwọn tálákà ń wá omi, àmọ́ kò sí rárá. Òùngbẹ ti mú kí ahọ́n wọn gbẹ.+ Èmi Jèhófà máa dá wọn lóhùn.+ Èmi Ọlọ́run Ísírẹ́lì ò ní fi wọ́n sílẹ̀.+ Jeremáyà 31:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wọ́n á wá pẹ̀lú ẹkún.+ Màá máa darí wọn bí wọ́n ṣe ń wá ojú rere. Màá ṣamọ̀nà wọn lọ sí ìṣàn* omi,+Lórí ọ̀nà tó tẹ́jú tí wọn ò ti ní kọsẹ̀. Nítorí èmi ni Bàbá Ísírẹ́lì, Éfúrémù sì ni àkọ́bí mi.”+
17 “Àwọn aláìní àti àwọn tálákà ń wá omi, àmọ́ kò sí rárá. Òùngbẹ ti mú kí ahọ́n wọn gbẹ.+ Èmi Jèhófà máa dá wọn lóhùn.+ Èmi Ọlọ́run Ísírẹ́lì ò ní fi wọ́n sílẹ̀.+
9 Wọ́n á wá pẹ̀lú ẹkún.+ Màá máa darí wọn bí wọ́n ṣe ń wá ojú rere. Màá ṣamọ̀nà wọn lọ sí ìṣàn* omi,+Lórí ọ̀nà tó tẹ́jú tí wọn ò ti ní kọsẹ̀. Nítorí èmi ni Bàbá Ísírẹ́lì, Éfúrémù sì ni àkọ́bí mi.”+