Òwe 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ọlọ́gbọ́n máa ń fetí sílẹ̀, á sì kọ́ ẹ̀kọ́ sí i;+Olóye máa ń gba ìtọ́sọ́nà ọlọgbọ́n+ 2 Tímótì 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 àti pé láti kékeré jòjòló + lo ti mọ ìwé mímọ́,+ èyí tó lè mú kí o di ọlọ́gbọ́n kí o lè rí ìgbàlà nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Kristi Jésù.+
5 Ọlọ́gbọ́n máa ń fetí sílẹ̀, á sì kọ́ ẹ̀kọ́ sí i;+Olóye máa ń gba ìtọ́sọ́nà ọlọgbọ́n+ 2 Tímótì 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 àti pé láti kékeré jòjòló + lo ti mọ ìwé mímọ́,+ èyí tó lè mú kí o di ọlọ́gbọ́n kí o lè rí ìgbàlà nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Kristi Jésù.+
15 àti pé láti kékeré jòjòló + lo ti mọ ìwé mímọ́,+ èyí tó lè mú kí o di ọlọ́gbọ́n kí o lè rí ìgbàlà nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Kristi Jésù.+