1 Sámúẹ́lì 25:32, 33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ni Dáfídì bá sọ fún Ábígẹ́lì pé: “Ìyìn ni fún Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, tí ó rán ọ wá pàdé mi lónìí yìí! 33 Ìbùkún sì ni fún làákàyè rẹ! Kí Ọlọ́run bù kún ọ torí o ò jẹ́ kí n jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀+ lónìí, o ò sì jẹ́ kí n fi ọwọ́ ara mi gbẹ̀san.* Òwe 24:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ìtọ́sọ́nà ọlọgbọ́n ni kí o fi ja ogun rẹ,+Nípasẹ̀ ọ̀pọ̀ agbani-nímọ̀ràn,* ìṣẹ́gun* á wà.+
32 Ni Dáfídì bá sọ fún Ábígẹ́lì pé: “Ìyìn ni fún Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, tí ó rán ọ wá pàdé mi lónìí yìí! 33 Ìbùkún sì ni fún làákàyè rẹ! Kí Ọlọ́run bù kún ọ torí o ò jẹ́ kí n jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀+ lónìí, o ò sì jẹ́ kí n fi ọwọ́ ara mi gbẹ̀san.*