Sáàmù 119:127 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 127 Ìdí nìyẹn tí mo fi nífẹ̀ẹ́ àwọn àṣẹ rẹJu wúrà, kódà ju wúrà tó dára* lọ.+ Òwe 8:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ gba ìbáwí mi dípò fàdákà,Àti ìmọ̀ dípò wúrà tó dára jù lọ,+