Sáàmù 119:103 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 103 Àwọn ọ̀rọ̀ rẹ mà dùn mọ́ òkè ẹnu mi o,Ó dùn ju oyin lọ lẹ́nu mi!+ Òwe 16:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọ̀rọ̀ dídùn jẹ́ afárá oyin,Ó dùn mọ́ ọkàn,* ó sì ń wo egungun sàn.+