ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 4:20-22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Ọmọ mi, fetí sí àwọn ọ̀rọ̀ mi;

      Fetí sílẹ̀ dáadáa* sí àwọn ọ̀rọ̀ mi.

      21 Máa fi wọ́n sọ́kàn;

      Jẹ́ kí wọ́n jinlẹ̀ lọ́kàn rẹ,+

      22 Nítorí ìyè ni wọ́n jẹ́ fún àwọn tó wá wọn rí+

      Wọ́n sì jẹ́ ìlera fún gbogbo ara* wọn.

  • Òwe 12:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ọ̀rọ̀ téèyàn sọ láìronú dà bí ìgbà tí idà gúnni,

      Àmọ́ ahọ́n ọlọ́gbọ́n ń woni sàn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́