Lúùkù 22:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Àmọ́ ìdààmú bá a gan-an débi pé ṣe ló túbọ̀ ń gbàdúrà taratara;+ òógùn rẹ̀ sì dà bí ẹ̀jẹ̀ tó ń kán sílẹ̀. Jòhánù 12:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ní báyìí, ìdààmú bá mi,*+ kí sì ni kí n sọ? Baba, gbà mí kúrò nínú wákàtí yìí.+ Síbẹ̀, torí èyí ni mo fi wá sí wákàtí yìí.
44 Àmọ́ ìdààmú bá a gan-an débi pé ṣe ló túbọ̀ ń gbàdúrà taratara;+ òógùn rẹ̀ sì dà bí ẹ̀jẹ̀ tó ń kán sílẹ̀.
27 Ní báyìí, ìdààmú bá mi,*+ kí sì ni kí n sọ? Baba, gbà mí kúrò nínú wákàtí yìí.+ Síbẹ̀, torí èyí ni mo fi wá sí wákàtí yìí.