Àìsáyà 53:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí ìyẹn, màá fún un ní ìpín láàárín ọ̀pọ̀lọpọ̀,Ó sì máa pín ẹrù ogun pẹ̀lú àwọn alágbára,Torí ó tú ẹ̀mí* rẹ̀ jáde, àní títí dé ikú,+Wọ́n sì kà á mọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀;+Ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn,+Ó sì bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bẹ̀bẹ̀.+ 1 Kọ́ríńtì 15:3, 4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí lára àwọn ohun tí mo kọ́kọ́ fi lé yín lọ́wọ́ ni ohun tí èmi náà gbà, pé Kristi kú nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa bí Ìwé Mímọ́ ṣe sọ;+ 4 àti pé a sin ín,+ bẹ́ẹ̀ ni, pé a jí i dìde+ ní ọjọ́ kẹta+ bí Ìwé Mímọ́ ṣe sọ;+
12 Torí ìyẹn, màá fún un ní ìpín láàárín ọ̀pọ̀lọpọ̀,Ó sì máa pín ẹrù ogun pẹ̀lú àwọn alágbára,Torí ó tú ẹ̀mí* rẹ̀ jáde, àní títí dé ikú,+Wọ́n sì kà á mọ́ àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀;+Ó ru ẹ̀ṣẹ̀ ọ̀pọ̀ èèyàn,+Ó sì bá àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ bẹ̀bẹ̀.+
3 Nítorí lára àwọn ohun tí mo kọ́kọ́ fi lé yín lọ́wọ́ ni ohun tí èmi náà gbà, pé Kristi kú nítorí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa bí Ìwé Mímọ́ ṣe sọ;+ 4 àti pé a sin ín,+ bẹ́ẹ̀ ni, pé a jí i dìde+ ní ọjọ́ kẹta+ bí Ìwé Mímọ́ ṣe sọ;+