Sáàmù 40:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jọ̀ọ́ Jèhófà, jẹ́ kó wù ọ́ láti gbà mí sílẹ̀.+ Jèhófà, tètè wá ràn mí lọ́wọ́.+