Sáàmù 19:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Òfin Jèhófà pé,+ ó ń sọ agbára dọ̀tun.*+ Ìránnilétí Jèhófà ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé,+ ó ń sọ aláìmọ̀kan di ọlọ́gbọ́n.+ Sáàmù 51:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Dá ayọ̀ ìgbàlà rẹ pa dà fún mi;+Kí o sì jẹ́ kó máa wù mí láti ṣègbọràn sí ọ.*
7 Òfin Jèhófà pé,+ ó ń sọ agbára dọ̀tun.*+ Ìránnilétí Jèhófà ṣeé gbẹ́kẹ̀ lé,+ ó ń sọ aláìmọ̀kan di ọlọ́gbọ́n.+