Sáàmù 22:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ á jẹ, wọ́n á sì yó;+Àwọn tó ń wá Jèhófà yóò yìn ín.+ Kí wọ́n gbádùn ayé* títí láé. Sáàmù 31:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Oore rẹ mà pọ̀ o!+ O ti tò wọ́n jọ fún àwọn tó bẹ̀rù rẹ,+O sì ti fi wọ́n hàn lójú gbogbo èèyàn, nítorí àwọn tó fi ọ́ ṣe ibi ààbò.+
26 Àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ á jẹ, wọ́n á sì yó;+Àwọn tó ń wá Jèhófà yóò yìn ín.+ Kí wọ́n gbádùn ayé* títí láé.
19 Oore rẹ mà pọ̀ o!+ O ti tò wọ́n jọ fún àwọn tó bẹ̀rù rẹ,+O sì ti fi wọ́n hàn lójú gbogbo èèyàn, nítorí àwọn tó fi ọ́ ṣe ibi ààbò.+