-
Sáàmù 91:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Nítorí yóò gbà ọ́ lọ́wọ́ pańpẹ́ pẹyẹpẹyẹ,
Lọ́wọ́ àjàkálẹ̀ àrùn tó ń pani run.
-
-
Sáàmù 124:6-8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ìyìn ni fún Jèhófà,
Torí kò fi wá ṣe ẹran ìjẹ fún eyín wọn.
8 Ìrànlọ́wọ́ wa wà nínú orúkọ Jèhófà,+
Aṣẹ̀dá ọ̀run àti ayé.”
-