Sáàmù 25:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ó dájú pé ojú ò ní ti ìkankan nínú àwọn tó nírètí nínú rẹ,+Àmọ́ ojú á ti àwọn tó jẹ́ oníbékebèke láìnídìí.+ Sáàmù 62:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ní tòótọ́, mo* dúró jẹ́ẹ́ de Ọlọ́run+Nítorí pé ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni ìrètí mi ti wá.+
3 Ó dájú pé ojú ò ní ti ìkankan nínú àwọn tó nírètí nínú rẹ,+Àmọ́ ojú á ti àwọn tó jẹ́ oníbékebèke láìnídìí.+