Àìsáyà 10:17, 18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ìmọ́lẹ̀ Ísírẹ́lì+ máa di iná,+Ẹni Mímọ́ rẹ̀ sì máa di ọwọ́ iná;Ó máa jó àwọn èpò àtàwọn igi ẹlẹ́gùn-ún rẹ̀ run ní ọjọ́ kan. 18 Ó máa mú ògo igbó rẹ̀ àti ọgbà eléso rẹ̀ kúrò pátápátá;*Ó máa dà bí ìgbà tí ẹni tó ń ṣàìsàn ń kú lọ.+ Ìsíkíẹ́lì 20:47 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 47 Sọ fún igbó tó wà ní gúúsù pé, ‘Gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà. Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Èmi yóò dáná sun ọ́,+ yóò sì jó gbogbo igi tútù àti gbogbo igi gbígbẹ inú rẹ run. Iná tó ń jó náà kò ní kú,+ yóò sì jó gbogbo ojú láti gúúsù dé àríwá.
17 Ìmọ́lẹ̀ Ísírẹ́lì+ máa di iná,+Ẹni Mímọ́ rẹ̀ sì máa di ọwọ́ iná;Ó máa jó àwọn èpò àtàwọn igi ẹlẹ́gùn-ún rẹ̀ run ní ọjọ́ kan. 18 Ó máa mú ògo igbó rẹ̀ àti ọgbà eléso rẹ̀ kúrò pátápátá;*Ó máa dà bí ìgbà tí ẹni tó ń ṣàìsàn ń kú lọ.+
47 Sọ fún igbó tó wà ní gúúsù pé, ‘Gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà. Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Èmi yóò dáná sun ọ́,+ yóò sì jó gbogbo igi tútù àti gbogbo igi gbígbẹ inú rẹ run. Iná tó ń jó náà kò ní kú,+ yóò sì jó gbogbo ojú láti gúúsù dé àríwá.