Sáàmù 62:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 62 Ní tòótọ́, mo* dúró jẹ́ẹ́ de Ọlọ́run. Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni ìgbàlà mi ti wá.+ Ìdárò 3:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ó dájú pé o* máa rántí, wàá sì bẹ̀rẹ̀ mọ́lẹ̀ kí o lè ràn mí lọ́wọ́.+ 21 Mo rántí èyí nínú ọkàn mi; ìdí nìyẹn tí màá ṣe fi sùúrù dúró dè ọ́.+ Míkà 7:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ ní tèmi, èmi yóò máa retí Jèhófà.+ Màá dúró* de Ọlọ́run ìgbàlà mi.+ Ọlọ́run mi yóò gbọ́ mi.+
20 Ó dájú pé o* máa rántí, wàá sì bẹ̀rẹ̀ mọ́lẹ̀ kí o lè ràn mí lọ́wọ́.+ 21 Mo rántí èyí nínú ọkàn mi; ìdí nìyẹn tí màá ṣe fi sùúrù dúró dè ọ́.+