- 
	                        
            
            Sáàmù 57:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        Wọ́n ti gbẹ́ kòtò dè mí, Àmọ́ àwọn fúnra wọn kó sínú rẹ̀.+ (Sélà) 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 141:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        10 Àwọn ẹni burúkú lápapọ̀ yóò já sínú àwọ̀n tí àwọn fúnra wọn dẹ,+ Èmi á sì kọjá lọ láìséwu. 
 
-