2 Sámúẹ́lì 16:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Dáfídì bá sọ fún Ábíṣáì àti gbogbo ìránṣẹ́ rẹ̀ pé: “Ẹ wò ó, ọmọ tèmi, tó ti ara mi wá ń wọ́nà láti gba ẹ̀mí* mi,+ ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ ti ẹni tó wá láti ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì!+ Ẹ fi sílẹ̀, kó máa ṣépè fún mi, torí Jèhófà ti sọ fún un pé kó ṣe bẹ́ẹ̀!
11 Dáfídì bá sọ fún Ábíṣáì àti gbogbo ìránṣẹ́ rẹ̀ pé: “Ẹ wò ó, ọmọ tèmi, tó ti ara mi wá ń wọ́nà láti gba ẹ̀mí* mi,+ ká má ṣẹ̀ṣẹ̀ wá sọ ti ẹni tó wá láti ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì!+ Ẹ fi sílẹ̀, kó máa ṣépè fún mi, torí Jèhófà ti sọ fún un pé kó ṣe bẹ́ẹ̀!