Sáàmù 32:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Níkẹyìn, mo jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi fún ọ;Mi ò bo àṣìṣe mi mọ́lẹ̀.+ Mo sọ pé: “Màá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ mi fún Jèhófà.”+ O sì dárí àṣìṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ mi jì mí.+ (Sélà) Sáàmù 38:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Gbogbo ara mi ń ṣàìsàn* nítorí ìbínú rẹ. Kò sí àlàáfíà nínú egungun mi nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mi.+ Òwe 28:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹni tó bá ń bo àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ kò ní ṣàṣeyọrí,+Àmọ́ ẹni tó bá jẹ́wọ́, tó sì fi wọ́n sílẹ̀ la ó fi àánú hàn sí.+
5 Níkẹyìn, mo jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi fún ọ;Mi ò bo àṣìṣe mi mọ́lẹ̀.+ Mo sọ pé: “Màá jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ mi fún Jèhófà.”+ O sì dárí àṣìṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ mi jì mí.+ (Sélà)
13 Ẹni tó bá ń bo àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ kò ní ṣàṣeyọrí,+Àmọ́ ẹni tó bá jẹ́wọ́, tó sì fi wọ́n sílẹ̀ la ó fi àánú hàn sí.+