- 
	                        
            
            Sáàmù 69:30, 31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        30 Màá kọ orin ìyìn sí orúkọ Ọlọ́run, Màá sì fi ọpẹ́ gbé e ga. 31 Èyí máa mú inú Jèhófà dùn ju akọ màlúù, Ju akọ ọmọ màlúù tó ní ìwo àti pátákò.+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Òwe 21:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        3 Kí èèyàn ṣe ohun tó dára tí ó sì tọ́ Máa ń mú inú Jèhófà dùn ju ẹbọ lọ.+ 
 
-