- 
	                        
            
            Sáàmù 9:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        17 Àwọn èèyàn burúkú á sá pa dà, wọ́n á sì forí lé Isà Òkú,* Gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tó gbàgbé Ọlọ́run. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Hósíà 4:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        6 A ó pa àwọn èèyàn mi lẹ́nu mọ́,* torí pé wọn kò ní ìmọ̀. 
 
-