-
Sáàmù 106:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Wọ́n gbàgbé Ọlọ́run,+ Olùgbàlà wọn,
Ẹni tó ṣe àwọn ohun ńlá ní Íjíbítì,+
-
Jeremáyà 18:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Àmọ́ àwọn èèyàn mi ti gbàgbé mi.+
Torí pé wọ́n ń rú ẹbọ* sí àwọn ohun tí kò ní láárí,+
Wọ́n ń mú kí àwọn èèyàn fẹsẹ̀ kọ ní ọ̀nà wọn, àwọn ojú ọ̀nà àtijọ́,+
Láti rìn ní ọ̀nà gbágungbàgun, ọ̀nà tí kò dán, tí kò sì tẹ́jú,*
-
Hósíà 8:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Àmọ́ màá sọ iná sí àwọn ìlú rẹ̀,
Á sì jó àwọn ilé gogoro ìlú kọ̀ọ̀kan run.”+
-
-
-
-
-