-
Lúùkù 14:31, 32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Àbí ọba wo, tó fẹ́ lọ bá ọba míì jagun, ni kò ní kọ́kọ́ jókòó, kó sì gba ìmọ̀ràn láti mọ̀ bóyá òun máa lè fi ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ọmọ ogun gbéjà ko ẹni tó ń kó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ogún (20,000) bọ̀ wá bá a jà? 32 Ní tòótọ́, tí kò bá lè ṣe bẹ́ẹ̀, á jẹ́ pé nígbà tí ọ̀nà ẹni yẹn ṣì jìn, ó máa rán àwọn ikọ̀ lọ, á sì bẹ̀bẹ̀ fún àlàáfíà.
-