Oníwàásù 12:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ọ̀rọ̀ àwọn ọlọ́gbọ́n dà bí ọ̀pá kẹ́sẹ́ màlúù,+ àkójọ ọ̀rọ̀ wọn sì dà bí ìṣó tó wọlé ṣinṣin; ọ̀dọ̀ olùṣọ́ àgùntàn kan ni wọ́n ti wá.
11 Ọ̀rọ̀ àwọn ọlọ́gbọ́n dà bí ọ̀pá kẹ́sẹ́ màlúù,+ àkójọ ọ̀rọ̀ wọn sì dà bí ìṣó tó wọlé ṣinṣin; ọ̀dọ̀ olùṣọ́ àgùntàn kan ni wọ́n ti wá.