Òwe 7:22, 23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Lójijì, ó tẹ̀ lé obìnrin náà, bí akọ màlúù tí wọ́n ń mú lọ síbi tí wọ́n ti fẹ́ pa á,Bí òmùgọ̀ tí wọ́n fẹ́ fìyà jẹ nínú àbà,*+23 Títí ọfà fi gún ẹ̀dọ̀ rẹ̀ ní àgúnyọ;Bí ẹyẹ tó kó sínú pańpẹ́, kò mọ̀ pé ẹ̀mí òun máa lọ sí i.+
22 Lójijì, ó tẹ̀ lé obìnrin náà, bí akọ màlúù tí wọ́n ń mú lọ síbi tí wọ́n ti fẹ́ pa á,Bí òmùgọ̀ tí wọ́n fẹ́ fìyà jẹ nínú àbà,*+23 Títí ọfà fi gún ẹ̀dọ̀ rẹ̀ ní àgúnyọ;Bí ẹyẹ tó kó sínú pańpẹ́, kò mọ̀ pé ẹ̀mí òun máa lọ sí i.+