-
Òwe 5:8-11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Jìnnà réré sí i;
Má sì sún mọ́ ẹnu ọ̀nà ilé rẹ̀,+
9 Kí o má bàa fi iyì rẹ fún àwọn ẹlòmíì+
Tàbí kí o fi ọ̀pọ̀ ọdún kórè ohun tó burú;+
10 Kí àwọn àjèjì má bàa fa ọrọ̀* rẹ gbẹ,+
Kí àwọn ohun tí o ṣiṣẹ́ kára fún sì lọ sí ilé àjèjì.
11 Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, wàá kérora nígbẹ̀yìn ayé rẹ
Nígbà tí okun rẹ bá tán, tí ẹran ara rẹ sì gbẹ+
-