Orin Sólómọ́nì 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Olólùfẹ́ mi dà bí egbin, bí akọ ọmọ àgbọ̀nrín.+ Òun nìyẹn, ó dúró sí ẹ̀yìn ògiri wa,Ó ń yọjú lójú fèrèsé,* Ó ń yọjú níbi àwọn fèrèsé tó ní asẹ́ onígi.
9 Olólùfẹ́ mi dà bí egbin, bí akọ ọmọ àgbọ̀nrín.+ Òun nìyẹn, ó dúró sí ẹ̀yìn ògiri wa,Ó ń yọjú lójú fèrèsé,* Ó ń yọjú níbi àwọn fèrèsé tó ní asẹ́ onígi.