- 
	                        
            
            Orin Sólómọ́nì 8:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        14 “Tètè, olólùfẹ́ mi, Kí o sì yára bí egbin+ Tàbí akọ ọmọ àgbọ̀nrín Lórí àwọn òkè tó ní ewé tó ń ta sánsán.” 
 
- 
                                        
14 “Tètè, olólùfẹ́ mi,
Kí o sì yára bí egbin+
Tàbí akọ ọmọ àgbọ̀nrín
Lórí àwọn òkè tó ní ewé tó ń ta sánsán.”