ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 26:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Lẹ́yìn àkókò díẹ̀, Ábímélékì ọba àwọn Filísínì ń wo ìta látojú fèrèsé,* ó sì rí Ísákì tó ń bá Rèbékà ìyàwó rẹ̀ tage.*+

  • Jẹ́nẹ́sísì 29:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Jékọ́bù wá fi ọdún méje ṣiṣẹ́ fún Lábánì nítorí Réṣẹ́lì,+ àmọ́ bí ọjọ́ díẹ̀ ló rí lójú rẹ̀ torí ìfẹ́ tó ní fún Réṣẹ́lì.

  • Orin Sólómọ́nì 8:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Gbé mi lé ọkàn rẹ bí èdìdì,

      Bí èdìdì ní apá rẹ,

      Torí ìfẹ́ lágbára bí ikú,+

      Ìṣòtítọ́ sì lágbára bí Isà Òkú.*

      Ọwọ́ iná rẹ̀ dà bí iná tó ń jó, ọwọ́ iná Jáà.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́