Diutarónómì 4:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí iná tó ń jóni run ni Jèhófà Ọlọ́run yín,+ Ọlọ́run tó fẹ́ kí ẹ máa jọ́sìn òun nìkan ṣoṣo.+ 1 Jòhánù 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹnikẹ́ni tí kò bá nífẹ̀ẹ́ kò tíì mọ Ọlọ́run, torí Ọlọ́run jẹ́ ìfẹ́.+