Sáàmù 7:14-16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Wo ẹni tó lóyún ìwà ìkà;Ọmọ* ìjàngbọ̀n wà nínú rẹ̀, ó sì bí èké.+ 15 Ó ti wa kòtò, ó sì gbẹ́ ẹ jìn,Àmọ́ ó já sínú ihò tí òun fúnra rẹ̀ gbẹ́.+ 16 Wàhálà tó dá sílẹ̀ á pa dà sí orí òun fúnra rẹ̀;+Ìwà ipá rẹ̀ á sì já lé àtàrí rẹ̀. Gálátíà 6:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tàn yín jẹ: Ọlọ́run kò ṣeé tàn.* Nítorí ohun tí èèyàn bá gbìn, òun ló máa ká;+
14 Wo ẹni tó lóyún ìwà ìkà;Ọmọ* ìjàngbọ̀n wà nínú rẹ̀, ó sì bí èké.+ 15 Ó ti wa kòtò, ó sì gbẹ́ ẹ jìn,Àmọ́ ó já sínú ihò tí òun fúnra rẹ̀ gbẹ́.+ 16 Wàhálà tó dá sílẹ̀ á pa dà sí orí òun fúnra rẹ̀;+Ìwà ipá rẹ̀ á sì já lé àtàrí rẹ̀.
7 Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni tàn yín jẹ: Ọlọ́run kò ṣeé tàn.* Nítorí ohun tí èèyàn bá gbìn, òun ló máa ká;+