Òwe 30:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Àwọn ohun mẹ́rin kan wà lára àwọn ohun tó kéré jù lọ ní ayé,Àmọ́ tí wọ́n ní ọgbọ́n àdámọ́ni:*+ 25 Àwọn èèrà jẹ́ ẹ̀dá* tí kò lágbára,Síbẹ̀, wọ́n ń kó oúnjẹ wọn jọ nígbà ẹ̀ẹ̀rùn.+
24 Àwọn ohun mẹ́rin kan wà lára àwọn ohun tó kéré jù lọ ní ayé,Àmọ́ tí wọ́n ní ọgbọ́n àdámọ́ni:*+ 25 Àwọn èèrà jẹ́ ẹ̀dá* tí kò lágbára,Síbẹ̀, wọ́n ń kó oúnjẹ wọn jọ nígbà ẹ̀ẹ̀rùn.+