Jóòbù 35:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ó ń kọ́ wa+ ju àwọn ẹranko orí ilẹ̀+ lọ,Ó sì ń mú ká gbọ́n ju àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run lọ.