Òwe 5:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jìnnà réré sí i;Má sì sún mọ́ ẹnu ọ̀nà ilé rẹ̀,+ 9 Kí o má bàa fi iyì rẹ fún àwọn ẹlòmíì+Tàbí kí o fi ọ̀pọ̀ ọdún kórè ohun tó burú;+
8 Jìnnà réré sí i;Má sì sún mọ́ ẹnu ọ̀nà ilé rẹ̀,+ 9 Kí o má bàa fi iyì rẹ fún àwọn ẹlòmíì+Tàbí kí o fi ọ̀pọ̀ ọdún kórè ohun tó burú;+