Òwe 6:33-35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ọgbẹ́ àti àbùkù ló máa gbà,+Ìtìjú rẹ̀ kò sì ní pa rẹ́.+ 34 Nítorí owú máa ń mú kí ọkọ bínú;Kò ní ṣojú àánú nígbà tó bá ń gbẹ̀san.+ 35 Kò ní gba àsandípò;*Láìka bí ẹ̀bùn náà ṣe pọ̀ tó, kò ní tù ú lójú. Òwe 7:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Títí ọfà fi gún ẹ̀dọ̀ rẹ̀ ní àgúnyọ;Bí ẹyẹ tó kó sínú pańpẹ́, kò mọ̀ pé ẹ̀mí òun máa lọ sí i.+
33 Ọgbẹ́ àti àbùkù ló máa gbà,+Ìtìjú rẹ̀ kò sì ní pa rẹ́.+ 34 Nítorí owú máa ń mú kí ọkọ bínú;Kò ní ṣojú àánú nígbà tó bá ń gbẹ̀san.+ 35 Kò ní gba àsandípò;*Láìka bí ẹ̀bùn náà ṣe pọ̀ tó, kò ní tù ú lójú.