Òwe 10:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àwọn ọlọ́gbọ́n máa ń fi ìmọ̀ ṣe ìṣúra,+Àmọ́ ẹnu àwọn òmùgọ̀ máa ń fa ìparun.+