Òwe 6:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ẹni tó bá bá obìnrin ṣe àgbèrè kò ní làákàyè;*Ẹni tó bá ṣe bẹ́ẹ̀ ń fa ìparun bá ara* rẹ̀.+ Òwe 9:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “Kí ẹni tó bá jẹ́ aláìmọ̀kan wọlé síbí.” Ó sọ fún àwọn tí kò ní làákàyè* pé:+ 17 “Omi tí a jí gbé máa ń dùn,Oúnjẹ tí a sì jẹ ní ìkọ̀kọ̀ máa ń gbádùn mọ́ni.”+
16 “Kí ẹni tó bá jẹ́ aláìmọ̀kan wọlé síbí.” Ó sọ fún àwọn tí kò ní làákàyè* pé:+ 17 “Omi tí a jí gbé máa ń dùn,Oúnjẹ tí a sì jẹ ní ìkọ̀kọ̀ máa ń gbádùn mọ́ni.”+