ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 8:1-3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 8 Ǹjẹ́ ọgbọ́n ò máa ké jáde?

      Ṣé òye ò máa gbé ohùn rẹ̀ sókè?+

       2 Ní orí àwọn ibi gíga+ tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀nà,

      Ó dúró ní àwọn oríta.

       3 Lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn ẹnubodè tó wọnú ìlú,

      Ní àtiwọ àwọn ẹnu ọ̀nà,

      Ó ń ké tantan pé:+

  • Òwe 9:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Ọgbọ́n tòótọ́ ti kọ́ ilé rẹ̀;

      Ó ti gbẹ́ òpó rẹ̀ méjèèje.

  • Òwe 9:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ó ti rán àwọn ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ jáde

      Láti ké jáde látorí àwọn ibi gíga ìlú pé:+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́