Òwe 1:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ọgbọ́n tòótọ́+ ń ké jáde ní ojú ọ̀nà.+ Ó ń gbé ohùn rẹ̀ sókè ní àwọn ojúde ìlú.+ 21 Ó ké jáde ní igun* ọ̀nà tí ọ̀pọ̀ èèyàn ń gbà. Ní àtiwọ àwọn ẹnubodè ìlú, ó ń sọ pé:+
20 Ọgbọ́n tòótọ́+ ń ké jáde ní ojú ọ̀nà.+ Ó ń gbé ohùn rẹ̀ sókè ní àwọn ojúde ìlú.+ 21 Ó ké jáde ní igun* ọ̀nà tí ọ̀pọ̀ èèyàn ń gbà. Ní àtiwọ àwọn ẹnubodè ìlú, ó ń sọ pé:+