Òwe 11:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Èso olódodo jẹ́ igi ìyè,+Ẹni tó bá sì ń jèrè ọkàn* jẹ́ ọlọ́gbọ́n.+