Sáàmù 141:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Tí olódodo bá gbá mi, á jẹ́ pé ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí mi;+Tó bá bá mi wí, á dà bí òróró ní orí mi,+Tí orí mi kò ní kọ̀ láé.+ Mi ò ní dákẹ́ àdúrà kódà nígbà tí àjálù bá bá wọn. Ìfihàn 3:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “‘Gbogbo àwọn tí mo fẹ́ràn ni mò ń bá wí, tí mo sì ń tọ́ sọ́nà.+ Torí náà, jẹ́ onítara, kí o sì ronú pìwà dà.+
5 Tí olódodo bá gbá mi, á jẹ́ pé ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí mi;+Tó bá bá mi wí, á dà bí òróró ní orí mi,+Tí orí mi kò ní kọ̀ láé.+ Mi ò ní dákẹ́ àdúrà kódà nígbà tí àjálù bá bá wọn.
19 “‘Gbogbo àwọn tí mo fẹ́ràn ni mò ń bá wí, tí mo sì ń tọ́ sọ́nà.+ Torí náà, jẹ́ onítara, kí o sì ronú pìwà dà.+