Jeremáyà 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Màá fún yín ní àwọn olùṣọ́ àgùntàn tí ọkàn mi fẹ́,+ wọ́n á sì fi ìmọ̀ àti ìjìnlẹ̀ òye bọ́ yín.