Jóṣúà 7:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹni tí a bá rí ohun tí a máa pa run lọ́wọ́ rẹ̀, ṣe la máa dáná sun ún,+ òun àti gbogbo ohun tó jẹ́ tirẹ̀, torí pé ó ti da májẹ̀mú+ Jèhófà àti pé ó ti hùwà tó ń dójú tini ní Ísírẹ́lì.”’”
15 Ẹni tí a bá rí ohun tí a máa pa run lọ́wọ́ rẹ̀, ṣe la máa dáná sun ún,+ òun àti gbogbo ohun tó jẹ́ tirẹ̀, torí pé ó ti da májẹ̀mú+ Jèhófà àti pé ó ti hùwà tó ń dójú tini ní Ísírẹ́lì.”’”