Àìsáyà 48:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ká ní o fetí sí àwọn àṣẹ mi ni!+ Àlàáfíà rẹ ì bá dà bí odò,+Òdodo rẹ ì bá sì dà bí ìgbì òkun.+