Òwe 26:13-15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ọ̀lẹ ń sọ pé: “Ọmọ kìnnìún wà lójú ọ̀nà,Kìnnìún wà ní gbàgede ìlú!”+ 14 Ilẹ̀kùn ń yí lórí ìkọ́* rẹ̀,Ọ̀lẹ náà ń yí lórí ibùsùn rẹ̀.+ 15 Ọ̀lẹ ki ọwọ́ rẹ̀ bọ inú abọ́ oúnjẹ,Àmọ́, ó rẹ̀ ẹ́ débi pé kò lè gbé e pa dà sẹ́nu.+
13 Ọ̀lẹ ń sọ pé: “Ọmọ kìnnìún wà lójú ọ̀nà,Kìnnìún wà ní gbàgede ìlú!”+ 14 Ilẹ̀kùn ń yí lórí ìkọ́* rẹ̀,Ọ̀lẹ náà ń yí lórí ibùsùn rẹ̀.+ 15 Ọ̀lẹ ki ọwọ́ rẹ̀ bọ inú abọ́ oúnjẹ,Àmọ́, ó rẹ̀ ẹ́ débi pé kò lè gbé e pa dà sẹ́nu.+